Yoruba Language for Secondary School. Osun State Yoruba Scheme of Work JSS3, Ministry of Education – Schemeofwork.com
YORUBA LANGUAGE SCHEME OF WORK JSS3 FIRST TERM
STATE OF OSUN UNIFIED SCHEME OF WORK
| OSE | EKA EKO | ORI-ORO | ERONGBA | AKOONU | OHUN-ELO IKONI | ISE-OLUKO | ISE AKEKOO | IWE ITOKASI |
| 1 | Ede | Atunyewo ise odunto koja | Akekoo yoo salaye die lara ise odun to koja | Ede litireso ati asa | Orisirisi ibeere ati idahun | Se ibeere lori imo ateyinwa awon akekoo | Teti si ohun ti oluko n so daruko ohun ti won ti se koja | Gbogbo iwe ibeere ateyinwa. |
| 2 | Ede | Oro oruko ati oro aropo oruko ninu gbolohun | Akekoo yoo le so ise ti oro oruko ati oro aropo oruko n se ninu gbolohun | 1. oluwa Bolatito sun 2. oro aropo oruko. Mo myo | Kadiboodu ti a ti ko awon apeere gbolohun oro oruko ati oro aropo oruko si | Ko awon oro gbolohun to ni oro oruko ati oro aropo oruko sara patako | 1. feti si ohun ti oluko n ko won. 2. Lo gbolohun to ni oro oruko ati oro aropo oruko bii ti olu | Eko ede Yoruba titun iwe kin-in-ni. |
| litireso | Asayan iwe ewi | Akekoo yoo le 1. ke ewi naa danmoran 2. se idamo onaa ede ati isowolo ede inu ewi naa | 1. ewi kike 2. koko oro a je mo oro to n lo lawujo | Awon ohun ti ewi dale | 1. Ke ewi naa fun awon akekoo 2. salaye lori ewi ti a ke. | 1. ke ewi naa bi ti oluko 2. toka si onaa ede ati isowolo ede inu ewi. | Iwe ewi tijoba yan | |
| Asa | Didekun iwa ika si omonikeji | Akekoo yoo le 1. so die lara iwa ika si omonikeji ti o wopo latijo ati lode oni 2. so die lara onaa ti a le fi dekun iwa bee lawujo | 1. iwa ika si omonikeji latijo -n Ikonileru -ifinisofa -Fifi eniyan rubo abbl. | 1. kadiboodu ti a ayaworan si tabi 2. Iwe iroyin atigbadegba | 1. salaye ohun ti iwa ika si omonikeji je 2. se apeere iwa ika si omonikeji laye atijo | 1. Teti si alaye oluko 2. Kopa ninu ijiroro ti oluko n dari | ||
| 3 | ede | Onka Yoruba | Akekoo yoo le 1. ka onka Yoruba lati Egberun titi mde Egbewa | Onka lati 1,000 – 2000 | Kadiboodu ti a ko onka si | 1. ka onka naa fawon akekoo 2. koo soju patako 3. Je ki won koo sinu iwe won | 1. ka onka tele oluko 2. koo sinu iwe re | Oluwafemi Abati- Ilupale onka Adayeba Yoruba iwe kin-ni-ni |
| B | litireso | Asayan iwe ere onitan | Akekoo yoo le 1. Fa eko ti ere naa ko ni yo 2. Salaye ifiwaweda ibe 3. ilo ede abbl. | 1. Ibudo itan 2. Ahunpo itan 3. Ifiwaweda | 1. Iwe asayan 2. Ohun elo isere abbl. | 1. Dari akekoo lati ka ere onitan naa 2. Se ifaara lori onkowe ati ohun ti ere naa da le abbl. | 1. ka ere onitan naa ni owoowo 2. Jiroro lori isele eyi ti won ka | Iwe ere onitan ti ijoba yan. |
| D | Asa | Iwa ika | Akekoo yoo le 1. Ko nipa didekun iwa ika si omonikeji 2. Salaye iwa ika bi ohun abuku lawujo | Iwa ika si omonikeji lode oni jijinigbe, Ipaniyan, Ifomosowo, Lilu aya eni abb. | Aworan awon to n fiya je omonikeji won | 1. Salaye awon iwa ika si omonikeji lode oni pelu apeere 2. Dari ijiroro lori onaa ti a le gba dekun re | 1. Teti si alaye oluko 2. Beere ibeere lori ohun ti ko ba ye won | |
| 4 A | ede | Onka yoruba | Akekoo yoo le; 1. Ka onka Yoruba , yoo sit un le kaa bi ti ateyinwa | Onka lati ookanlegbewa titi de oke kan 2,001-20,000 | Kadiboodu ti a ko onka Yoruba si | 1. kaa fawon akekoo bii ti ateyinwa 2. Je ki won ko sinu iwe won | 1. Kaa tele oluko ni sise-n-tele 2. Beere ibeere lori ibi ti a n sise le | Oluwafemi Abati-Itupale onka Adayeba Yoruba iwe kin-ni-ni odun 2000 |
| B | litireso | Asayan iwe litireso apileko oloro geere | Akekoo yoo le 1. Sise lori apileko oloro geere lai si ikose 2. Ko ibeere ati idahun sile sinu iwe won | Itupale litireso apileko oloro geere | 1. Iwe asayan 2. Opolopo alaye 3. Eda itan abbl. 4. Awitunwi abbl. | 1. Kawe fun awon akekoo 2. Salaye kikun lori ibi kika naa | 1. Je ki won kawe ni akagba 2. To wo sona nibi to ye 3. Ibeere ati idahun lorisirisi | |
| D | Asa | Didekun iwa ika si omonikeji | Akekoo yoo le 1. So die lara iwa ika to wopo latijo ati lode oni 2. So die lara onaa tia le fi dekun iwa bee lawujo | 1. lilo omo ni ilokulo 2. Ipaniyan 3. Lilu iyawo ile eni bi eni lu bara. Onaa lati dekun re: 1. Gbigba Alafia laaye 2. fifi ara eni si ipo omonikeji 3. Agbofinro abbl. | 1. Aworan orisirisi 2. Iwe iroyin atigbadegba | 1. appere iwa ika si omonikeji lorisirisi 2. Ijiroro lori onaa ti a le gba lati dekun re | 1. Teti si alaye oluko 2. Kopa ninu ijiroro ti oluko n dari 3. Beere ibere lori ohun ti ko ye won | |
| 5A | Ede | Akoto | Akekoo yoo le; 1. ko akoto ode oni lai ni ikose kanaakan 2. dahun awon ibeere lori akoto | Akoto; Bi appere 1. Aiye=aye 2. Osohgbo=Osogbo 3. Ilesha=Ilesa abbl. | Kaadi pelebepelebe ti a ti ko oro kookan si | Apeere oro akoto lorisirisi | 1. Teti si alaye oluko 2. Sise lori akoto lorisirisi 3. Beere ibeere lori ibi ti a n sisie le | |
| B | litireso | Asayan iwe ere onitan | Akekoo yoo le 1. Fa eko ti ere naa ko o ni yo 2. Salaye awon onaa ede ati onaa isowolo ede | 1. Ela itan ati ifiwaweda 2. Onaa ede ati onaa isowolo ede | Iwe ere onitan | 1. Jiroro lori iwa eda itan pelu akekoo 2. Salaye ibayemu awon akoonu itan | 1. Soro lori eda itan ti won feran ati eyi ti won ko feran | |
| D | Asa | Esin ibile | Akekoo yoo le 1. Salaye nipa igbagbo awon Yoruba lori ohun mimo ninu esin ibile | Ohun mimo ninu esin ibile. Bi apeere (a) aso funfun (b)igbin (d) Omi ajipon abbl. | Aworan elesin ibile ninu aso funfun | Salaye lekun-un rere nipa igbagbo Yoruba nipa ohun mimo bi o ti suyo ninu esin ibile | 1. Teti ai alaye oluko 2. Kopa ninu ijiroro ti oluko n dari | |
| 6A | Ede | Ise oro oruko | Akekoo yoo le So ise ti oro oruko nse | 1. Oluwa; Bamidele ku Abo oro ise Adeola lo oja 2. Oro ise; Adeolu lo Eko | Kadiboodu ti a ko apeere gbolohun ti ati lo oro oruko | Ko orisirisi gbolohun ti o fi ise oro oruko han soju patako 2. Salaye kikun lori won | Se adako awon gbolohun ti oluko ko soju patako 2. Teti si alaye oluko | |
| B | litireso | Asayan iwe ewi | Akekoo yoo le; 1. kewi funra won lai si ikose kankan | 1. Ewi kike 2. Fa awon koko oro ibe yo | 1. Iwe ti a yan 2. Aworan ohun ti ewi dale | 1. Kewi seti akekoo 2. salaye lori ewi ti a ke 3. Fa koko oro jade 4. Salaye onaa ede inu ewi | 1. ke ewi naa tele oluko 2. Fi pensu fala si ibi ti won ti kiyesi koko oro 3. Toka si onaa ede kookan 4. Teti si alaye oluko | |
| D | Asa | Esin ibile | Akekoo yoo le so 1. Eewo orisa to jemo iwa mimo | Eewo orisa to je mo iwa mimo bi apeere otito, ododo abbl. | 1. Aworan elesin ibile ninu aso funfun 2. Owo eyo 3. Efun abbl. | 1. Fi igbagbo yii we tawon elesin miran | 1. Teti salaye oluko 2. Kopa ninu ijiroro ti oluko n dari | |
| 7A | Ede | Ise oro aropo oruko | Akekoo yoo le so ise ti oro aropo oruko n se ninu gbolohun | 1. Oluwa             Mo yo 2. Mo lo si oja abo 3. Bolanle lo si Eko Eyan 4. Baba arugbo ku. | Kadiboodu ti a ko apeere gbolohun oro aropo oruko si | 1. Ko orisirisi gbolohun ti o fi ise oro aropo oruko han soju patako | Teti si alaye oluko 2. Se adako awon gbolohun ti oluko ko | |
| B | Litireso | Asayan iwe ere onitan | Akekoo yoo le; 1. Fa eko ti ere naa ko ni yo 2. Se afiwe isele inu ere ati isele oju aye | 1. Koko oro 2. Ifiwaweda 3. Ilo ede | 1. Iwe asayan 2. Ohun elo isere | 1. Dari akekoo lati ka iwe ere onitan 2. Jiroro lori eda itan ati ifiwaweda won 3. Salaye lori ilo ede | 1. Ka ere onitan naa ni akagba 2. Fa eko ti won ri ko yo | Iwe ti ijoba yan |
| D | Asa | Esin ibile ohun mimo | Akekoo yoo le; 1. Daruko awon aworo/Olusin orisa ile wa | 1. ipo awon awororo kookan. 2. Oruko won gege bi olusin bi won se tele ra | Aworan awon elesin ibile ninu aso won | 1. Salaye awon awororo ni kookan ati ipa won ninu esin ibile 2. Fi won we ti elesin miran | 1. Teti si alaye oluko 2. Beere ibeere lori ibi ti a n sise le. | |
| 8A | Ede | fonoloji | Akekoo yoo le 1. Se iparoje/isunku lai si ikose 2. Dahun awon ibeere to suyo lori iparoje | Iparoje faweli ati konsonaanti ninu oro. Bi apeere idahun= idaun 2. Ekuro=Ekuo abbl. | Kaadi pelebepelebe ti a ti se iparoje isunki | 1. ko orisirisi apeere soju patako 2. Se alaye kikun lori won | 1. Teti si alaye oluko 2. DSe adako awon iparoje/isunki ti oluko ko soju patako. | |
| B | litireso | Asayan iwe ewi | Akekoo yoo le 1. Da kewi funra won lai waala Kankan 2. Dahun ibeere lori ewi | Ewi kike 2. Ikora eni ni ijanu ninu igbesi aye odo abbl. | Iwe asayan | 1. Kewi seti awon akekoo 2. Fa koko oro inu ewi jade | 1. Kewi naa tele oluko 2. Fi pensu fala si ibi ti won ti kiyesi koko oro | Iwe asayan ewi |
| D | Asa | Aroko pipa | Akekoo yoo le 1. Mo itumo aroko kinni aroko? 2. Daruko orisirisi aroko to wa | 1. Ooya (Iyarun) 2. Isanaa; fifi isanaa ranse sile anaa abbl. | 1. orisirisi aroko ti Yoruba n pa sara won | Ko orisirisi aroko soju patako ati itumo ni kookan | 1. Teti si alaye oluko 2. Beere ibeere lori aroko 3. Se adako oju patako | |
| 9A | Ede | Fonoloji n tesiwaju | Akekoo yoo le 1. paroje ninu oro kookan lai si ikose 2. Se isunki oro lorisirisi | Bi apeere (1) Egungun=eegun 2. Agbakuro=agbakuo               Adeyehmi = Deyemi Iyanrin=yanrin | Kaadi pelebepelebe ti a ti ko awon oro kookan si | 1. ko orisirisi apeere soju patako 2. Salaye kikun lori won | 1. Teti si alaye oluko 2. Beere ibeere lori iparoje/ati isunki 3. Se adako awon oro oju patako | |
| B | litireso | Asayan iwe litireso oloro geere | Akekoo yoo le 1. sise lori litireso oloro geere. 2. Dahun awon ibeere to suyo | Itupale litireso oloro geere | 1. Iwe asayan 2. Ifiwaweda 3. Eda itan | 1. kawe fun awon akekoo 2. so ewa ede to jeyo | 1. teti si oluko daadaa 2. Kawe ni owoowo 3. Beere ibeere lori ibi kika | |
| D | Asa | Aroko n tesiwaju | Akekoo yoo le 1. Aroko aye atijo ati tode oni | 1. Okuta kiko le oja laye atijo tumo si iye ti won n taja Wonaa kowo sibe 2. Laye ode oni, jokoo ti oja re taa funra re | Orisirisi aroko aye atijo ati tode oni | 1. ko orisirisi aroko soju patako tatijo ati tode oni | 1. Teti si alaye oluko 2. Se adako oju patako sinu iwe | |
| 10a | Ede | Iseda oro oruko | Akekoo yoo le 1. Seda oro oruko funra won 2. Dahun awon ibeere to suyo | Iseda oro oruko bi apeere; 1. a +bo = abo 2. e +ro = ero 3. ai + gbon=aigbon awon ti a ko seda bi apeere omi abbl. | Kaadi pelebepelebe ti a ko oro ti a seda si | Orisirisi apeere 2. Beere ibeere lori ibi ti a n sise le | 1. Teti si alaye oluko 2. Beere ibeere 3. Se adako ise oluko | Eko ede titun. Iwe keta Atunse titun Oyebamiji Mustapha ati awon yookun 2009 |
| B | litireso | Asayan iwe ewi | Akekoo yoo le 1. kewi funra won bii ti oluko 2. Daruko isowolo ede inu ewi naa | 1. Ewi kike 2. Koko oro to je mo oro to n lo lawujo | Aworan ohun tewi da le | 1. kewi fawon akekoo 2. Salaye ewi ti a ke lekunrere | 1. Kewi ni kookan bi I ti oluko 2. Toka si ilo ede to suyo 3. Beere ibeere lori ib ti a n sisie le`  | |
| D | Asa | Aroko | Akekoo yoo le 1. Daruko orisirisi aroko ti a ni | Bi apeere; Bi ode ba f iota,etu-ibon ranse si ode miiran. Eyi tumo si ki o gba eni to ran gbo sododo ni 2. Jagunjagun n gbeyawo bo=isigun si ilu odikeji | Orisirisi apeere aroko | 1. ko apeere aroko soju patako ati itumo won | 1. Teti si alaye oluko 2. Se adako oju patako 3. Beere ibeere lori ibi ti a n sise le | Oyebamiji Mustapha ati awon yookun 2009 Eko ede titun. Iwe keta Atunse titun |
| 11 A B D | Ede Litireso Asa | Atunyewo Eko | Sise atunyewo eko saa yii | |||||
| 12 A B D | Ede Litireso Asa | Atunyewo Eko | Sise atunyewo eko saa yii |
Yoruba Language for Secondary School. Osun State Yoruba Scheme of Work JSS3, Ministry of Education – Schemeofwork.com
YORUBA LANGUAGE SCHEME OF WORK JSS3 SECOND TERM
STATE OF OSUN UNIFIED SCHEME OF WORK
GRADE 9-2ndTerm
| OSE | Ori Oro | Erongba | Akoonu Ise | Ohun elo ikoni | Oluko | Akeeko |
| 1 EDE -LITIRESO -ASA | Atunyewo ise saa to koja | Akekoo yoo le: Salaye die lara ise saa to koja | Ede litireso ati Asa | Orisirisi ibeere ati idahun | Se ibeere lori ise saa to koja | (1)teti si oun ti oluko n so (2)daruko oun ti won ti se koja |
| 2 A EDE | Iseda oro oruko | Akekoo yoo le: (1)seda oro oruko funra won (2)dahun awon ibeere to suyo | Iseda oro oruko bii: Lilo afomo ibeere: Ai+san=aisan Alai+san=alaisan Afomo aarin (1)ki=ile+ki+ile=ilekile (2)si=ile+si+ile=ilesiile (3)omo=omo+ki+omo=omokomo abbl | Kaadi pelebe pelebe ti a ti ko oro ti a seda si | (1)orisirisi apeere: (2)beere Ibeere lori ibi ti a n sise le | (1)Teti si alaye oluko (2)beere ibeere (3)se adako ise oluko |
| B litireso | Asayan iwe itan aroso oloro geere | Akekoo yoo le: Sise lori iwe itan aroso oloro geere | Itupale litireso apileko itan aroso oloro geere | (1)iwe asayan (2)opolopo alaye (3)eda itan (4)auntunun (5)ifiwaweda | (1)kawe fun awon akekoo (2)salaye kikun fun won lori ibi kika naa | (1)kawe ni owo owo (2)ibeere ati idahun lorisirisi (3)se adako ise oluko |
| D ASA | Itoju alaboyun oyun nini dide ati itoju oyun | Akekoo yoo le: (1)salaye itoju oyun nini,dide ati itoju oyun | (1)oyun nini (2)oyun dide (3)itoju oyun | (1)aworan obinrin to wa ninu oyun | (1)salaye fawon akekoo nipa ise yii (2)beere ibeere lori ibi ti a n sise le | (1)teti si alaye oluko (2)beere ibeere lori oun ti ko ba ye won |
| 4 EDE | Iseda oro | Akekoo yoo le (1)seda oro nipa sise akanpo oro | Iseda oro nipa sise akanpo oro.Bi apeere: -ade+ni+iyi=adeniyi -ifa+ni+ade=ifalade(falade) | (1)orisirisi apeere (2)ibeere beere (3)opolopo a laye | Salaye f’awon akekoo nipa iseda oro(akanpo) | -Teti si alaye oluko -beere ibeere lori ibi ti a n sise le |
| Litireso | Asayan iwe ewi | Akekoo yoo le: (1)ke ewi naa dan-moran (2)se idamo ona ede ati isowolo ede inu eun naa | (1)ewi kike (2)koko oro a jemo oro to n lo | Aworan oun ti ewi dale | (1)keun naa fun awon akekoo (2)salaye kikin lori ewi ti a ke | (1)ke ewi naa bi I ti oluko (2)toka si ona ede ati isowoto ede inu ewi |
| 6/7 A EDE | Awe Gbolohun | Akekoo yoo le: (1)salaye awe gbolohun (2)daun ibeere lori awe gbolohun | Awe gbolohun afarahe. Bi apeere Iyawo Ti mo fe dara (2)obe ti sade se dun | Orisirisi apeere | Apeere lorisirisi lori awe gbolohun afarahe | (1)teti si alaye oluko (2)beere ibeere lori ibi ti a n sise le (3)se adako awon oro oju patako |
| B Litireso | Asayan Iwe Ewi | Akekoo yoo le: (1)keun naa dan moran (2)koko oro a je mo oro to n lo lawujo | (1)ewi kike (2)koko oro a je mo oro to n lo lawujo | Aworan oun ti ewi dale | (1)Keun f’awon akekoo (2)fa koko oro jade (3)salaye ona ede inu ewi | (1)kewi ni kookan bii ti oluko (2)toka si ilo ede to suyo (3)beere ibere lori ibi ti a n sise le |
| D ASA | Ise abinibi ile yoruba | Akekoo yoo le: Daruko awon ise abinibi ile yoruba | Ise ebu: Sise adi ikoko abbl.mimo aro sise Ise ode- ode adedo ode adegbo abbl | Aworan lorisirisi tabi eyi ti a ya sinu kaadiboodu | (1)ko orisirisi ise abinibi soju patako (2)salaye okookan awon ise yii fawon akeeko | Teti si alaye oluko (2)bedere ibeere lori ibi ti a n sise le (3)se adako oun ti oluko ko soju patako |
| 8 A EDE | Awe gbolohun Afarahe/afibo | Akekoo yoo le: (1)salaye awe gbolohun afarahe/afibo | Awe gbolohun afarahe/afibo. Bi apeere oko ti mo fe rewa (2)ile ti mo ko tobi abbl | Orisirisi apeere | (1)salaye awe gbolohun afarahe/afibo lekun-un rere (2)apeere lorisirisi lori awe gbolohun afarahe/afibo | (1)teti si alaye oluko 2)beere ibeere lori ibi ti a n sise le (3)se adako awon oro oju patako |
| B Litireso | Asayan iwe ere onitan | Akekoo yoo le: (1)fa eko ti ere naa ko ni yo (2)se afiwe isele inu ere ati isele oju aye | (1)koko oro (2)ifiwaweda (3)ilo ede | (1)iwe asyan (2)oun elo isere | (1)dari akekoo lati ka iwe ere onitan (2)jiroro lori eda itan ati ifiwaweda won (3)salaye lori ilo ede | (1)ka ere onitan naa ni akagba (2)fa eko ti won ri ko yo |
| D Asa | Ise abinibi (ise owo lode oni) | Akekoo yo le: (1)daruko awon ise owo lode oni | Ise owo lode oni: Ajorin/agerun/aserun- Niyoyo aranso(amunidara) Ilo-konputa kapinta abbl | Orisirisi aworan ise owo ode oni | (1)salaye awon ise owo tode oni f’awon akekoo (2)ko awon ise owo ode oni soju patako (3)beere ibeere lowo akekoo nipa awon ise owo ode oni | (1)teti si alaye oluko (2)beere ibeere (3)se adako oun ti oluko ko soju patako |
| 9 A EDE | Ise gbolohun | Akekoo yoo le: (1)salaye ise gbolohun lekun-un rere (2)orisirisi gbolohun | Gbolohun alalaye Gbolohun ase bii apeere Dide,koko abbl Gbolohun ibeere | (1)orisirisi apeere (2)beere ibeere lori ibi ti a n sise le | Salaye f’awon akekoo nipa ise yii | (1)teti si alaye oluko (2)beere ibeere |
| B Litireso | Asayan iwe eun | Akekoo yoo le: (1)da kewi funra won lai si waala Kankan (2)daun awon ibeere to suyo | Eun kike ilo ede lorisirisi | Iwe asayan | (1)kewi seti awon akeekoo (2)fa koko oro inu ewi jade | (1)teti salaye oluko (2)beere ibeere lori ibi ti a n sise le |
| 10/11 A EDE | Awe gbolohun | Akekoo yoo le: (1)salaye awe gbolohun afarahe/afibo (2)daun awon ibeere lori gbolohun afarahe/afibo lai si ikose | Awe gbolohun afarahe/afibo Bi apeere (1)oko ayokele ti mo ra wulo pupo (2)iyan ti bosede gun nikoko | Orisirisi apeere | (1)salaye awe gbolohun afarahe/afibo fawon akekoo (2)se orisirisi apeere | (1)teti si alaye oliuko (2)beere ibeere (3)se adako awon oro oju patako |
| B Litireso | Asayan iwe litireso apileko oloro geere | Akekoo yoo lee: (1)sise lori litireso apileko oloro geere lai si waala kankan | Itupale litireso apileko oloro geere | (1)iwe asayan (2)opolopo alaye (3)ifiwaweda abbl | (1)kawe f’awon akekoo (2)salaye lekun-un rere nipa ise yii | (1)ki awon akekoo kawe ni akagba (2)ki won beere ibeere (3)se adako ise oju patako |
| D ASA | Owo sise(ipolowo oja) | Akekoo yoo le: (1)so ogbon ati ete ipolowo oja gege bi agunmu owo laye atijo ati lode oni | Ipolowo oja lorisirisi. Laye ode oni ati laye atijo | aworan awon to n ta,to n ra | (1)salaye ise yii faworan akekoo (2)fi aworan han won | Teti si alaye oluko Beere ibeere lorii ise yii |
| 12 A EDE B Litireso D ASA | Atunyewo eko | |||||
| 13 A EDE B Litireso D ASA | Idanwo ipari |
Yoruba Language for Secondary School. Osun State Yoruba Scheme of Work JSS3, Ministry of Education – Schemeofwork.com
YORUBA LANGUAGE SCHEME OF WORK JSS3 THIRD TERM
STATE OF OSUN UNIFIED SCHEME OF WORK
| OSE | EKA EKO | ORI-ORO | ERONGBA | AKOONU | OHUN-ELO IKONI | ISE-OLUKO | ISE AKEKOO | IWE ITOKASI |
| 1A | A Ede B litireso D Asa | Atunyewo ise saa to koja | Akekoo yoo le 1. Salaye die lara ise saa to koja 2. dahun awon ibeere to suyo | Ede. Litireso ati asa | Orisirisi ibeere ati idahun | Se ibeere lori saa to koja | 1. Teti si ohun ti oluko n so 2. daruko ohun ti won tise koja | Gbogbo ibeere ateyinwa |
| 2A | Ede | Apola ise | Akekoo yoo le Sise lori apola ise lai si ikose | Apola ise ihun apola ise | Orisirisi apeere | Salaye pelu orisirisi apeere | 1. Teti si alaye oluko 2. Beere ibeere 3. Se adako ise oluko | |
| B | litireso | Asayan iwe itan aroso oloro geere | Akekoo yoo le 1. sise lori iwe itan aroso oloro geere | Itupale litireso apileko itan aroso oloro geere | 1. Iwe asayan 2. Opolopo 3. Eda itan 4. Awitunwi 5. Ifiwaweda | 1. Kawe funaawon akekoo 2. Salaye kikun fun won lori ibi kika naa | 1. kawe ni owoowo 2. Beere ibeere 3. Se adako ise oluko | |
| D | Asa | Owe | Akekoo yoo le 1. powe funra won 2. so itandowe lorisirisi | 1. Owe lorisirisi 2. Itandowe | 1. Iwe owe 2. Orisirisi owe | 1. kinni owe 2. Salaye awon owe Yoruba fun awon akekoo 3. Powe opolopo fun won 4. Koo soju patako | 1. Teti si alaye oluko 2. Powe ni kookan lati kopa 3. Beere ibeere 4. Se adako oju patako | |
| 3A | Ede | Apola ise ati ise re ninu gbolohun | Akekoo yoo le; 1. Salaye apola ise 2. Pataki apola ise 3. Ilo apola ise | 1. Apola ise 2. Ise apola ise 3. Ilo apola ise | 1. Orisirisi apeere | 1. Salaye fawon akekoo nipa ilo apola ise 2. Beere ibeere | 1. Teti si oluko 2. So Pataki apola ise ninu gbolohun 3. Se adako ise yii | |
| B | litireso | Asayan iwe ewi | Akekoo yoo loe: 1. kewi naa dan-moran. 2. Se idamo onaa ede ati isowolo ede inu ewi naa | 1. Ewi kike 2. koko oro a jemo oro to n lo. | Aworan ohun ti ewi dale | 1. kewi naa fun awon akekoo 2. Salaye kikun lori ewi ti a ke | 1. Kewi naa bii ti oluko. 2. Toka si onaa ede ati isowolo ede inu ewi | Iwe ewi ti ijoba yan |
| D | Asa | Owe | Akekoo yoo le: 1. Powe funra won 2. So itumo owe | Owe lorisirisi. Iwulo owe Itumo owe kookan | Iwe owe | 1. So Itumo owe fawon akekoo 2. Powe fun won lorisirisi 3. So iwulo owe lorisirisi ati asiko ti a maa n powe kookan | 1. Teti si oluko 2. So iwulo owe 3. Beere ibeere 4. Se adako ise yii | |
| 4A | Ede | Aroko n tesiwaju Alariyanjiyan | Akekoo yoo le 1. Ko aroko lai si ikose 2. Dahun awon ibeere to ba suyo | Aroko alariyanjiyan. Ilapa ero. Ise oluko dara ju ise agbe lo Ise agbe ……… | Aroko alariyanjiyan Ilapa ero | 1. Salaye irufe aroko yii fawon akekoo 2. Beere ibeere lori ibi ti a n sise le. | 1. Teti si alaye oluko 2. Beere ibeere 3. Se adako ise oluko | |
| B | litireso | Asayan iwe ere onitan | Akekoo yoo le; 1. Fa eko ti ere naa ko ni yo 2. Se afiwe isele inu ere ati isele oju aye | 1. Kiko oro 2. Ifiwaweda 3. Ilo ede | 1. Iwe asayan 2. Ohun elo isere | 1. Dari akekoo lati ka iwe ere onitan 2. Jiroro lori eda itan ati ifiwaweda won 3. Salaye lori ilo ede | 1. Ka ere onitan naa ni akaye 2. Fa eko ti won ri ko yo. | Iwe ti ijoba yan. |
| D | Asa | Itoju ara eni | Akekoo yoo le; 1. Daruko awon onaa ti a n gba toju ara eni | Itoju ara eni imotooto | Aworan nipa eto ilera | 1. Salaye awon onaa ti a n gba toju ara eni tori ki aisan ma baa sewa. 2. Beere ibeere | 1. Teti si oluko 2. Beere ibeere 3. Se adako ohun ti oluko ko soju patako | |
| 5A | Ede | Aroko n tesiwaju Alariyanjiyan n tesiwaju | Akekoo yoo le; 1. Ko aroko lai si waala Kankan. 2. dahun awon ibeere to suyo | Aroko alariyanjiyan ilapa ero | Ilapa ero | 1. Salaye awon ilapa ero fawon akekoo 2. Beere ibeere 3. Ko ise won soju patako 4. Je ki won koo sinu iwe won | 1. Teti si alaye oluko 2. Beere ibeere lori aroko yii 3. Se adako awon oro oju patako | |
| B | litireso | Asayan iwe itan aroso oloro geere | Akekoo yoo le; 1. sise lori iwe itan aroso oloro geere | Itupale litireso apileko itan aroso oloro geere | 1. Iwe asayan 2. Opolopo alaye 3. Ede itan 4. Awitunwi 5. Ifiwaweda | 1. Kawe fawon akekoo 2. Salaye kikun funwon lori ibi kika naa | 1. Kowe ni akagba 2, Beere ibeere 3. Se adako ise oluko | |
| D | Asa | Itoju ara irun didi/kiko. Irun fifa/gige | Akekoo yoo le; 1. Se itoju irun won lore-koore 2. Pa ofin imototo mo | Itoju ara Itoju irun ori eni | Aworan irun didi, kiko ati irun gige | 1. Salaye ise yii fawon akekoo 2. Beere ibeere | 1. teti si alaye oluko 2. Beere ibeere 3. Se adako ise oluko | |
| 6A 7 | Ede | Aroko aroko oniroyin (Ilapa ero | Akekoo yoo le; 1. ko aroko oniroyin bi eni pe o soju mi pato 2. Dahun awon ibeere to suyo | Aroko oniroyin Ilapa ero | Aroko oniroyin | 1. Salaye aroko yii 2. Beere ibeere 3. To won sonaa | 1. Teti si alaye oluko 2. Beere ibeere 3. Se adako ise oluko | |
| B | litireso | Asayan iwe litireso apileko oloro geere | Akekoo yoo le 1. Sise lori litireso apileko oloro geere lai si ikose | Itupale litireso apileko oloro geere | 1. Iwe asayan 2. Opolopo alaye 3. Ifiwaweda abbl.  | 1. kowe fawon akekoo 2. Salaye lekun-un rere nipa ise yi | 1. Kawe ni akagba 2. Beere ibeere 3. Se adako ise oju patako | |
| D | Asa | Itoju ara eni Itoju aso, eekannaa owo ati eekanaa ese abbl. | Akekoo yoo le; 1. Salaye awon onaa ti a n gba se itoju aso, eekannaa abbl. | Itoju ara eni | Aworan nipa eto ilera | 1. Salaye nipa ise yii fawon akekoo 2. Beere ibeere | 1. Teti si alaye oluko 2. Beere ibeere 3. Se adako ise oju patako | |
| 8A 9 | Ede | Apola atokun ati ise re | Akekoo yoo le; 1. Salaye apola atokun lai si ikose | Apola atokun | Orisirisi apeere | 1. Salaye ise yii fawon akekoo pelu opolopo apeere 2. Beere ibeere | 1. Teti salaye oluko 2. Beere ibeere 3. Se adako awon oro oju patako | Oyebamiji Mustapha ati awon yooku Eko ede Yoruba titun iwe keta 2009 |
| B | litireso | Asayan iwe ere onitan | Akekoo yoo le; 1. Fa eko ti ere naa ko ni yo 2. Se afiwe isele inu ere ati isele oju aye | 1. koko oro 2. ifiwaweda 3. ilo ede | 1.  Iwe asayan 2. Ohun elo isere | 1. Dari awon akekoo lati ka iwe ere onitan 2. Jiroro lori eda itan ati ilo ede | 1. ka ere onitan naa ni owoowo 2. ka eko ti won ri ko yo | |
| D | Asa | Eru ati iwofa | Akekoo yoo le; 1. Salaye onaa nini eru ati yiya iwofa laye atijo 2. dahun ibeere to ba suyo | Awon eru laye atijo 2. awon iwofa | Aworan to ba mu | 1. Salaye eru nini ati iwofa yiya fawon akekoo 2. Beere ibeere | 1. Teti salaye oluko 2. Beere ibeere 3. Se adako ohun ti oluko ko soju patako | |
| 10A 11 | Ede | Apola ise n tesiwaju | Akekoo yoo le; Sise lori apola Ise lai si waala | Apola ise ihun apola ise | Orisirisi apeere | Salaye pelu orisirisi apeere | 1. Teti alaye oluko 2. Beere ibeere. 3. Se adako ise oluko | |
| B | Asa | Eru ati iwofa Fifi-ni seru lode oni ati ilokulo omo | Akekoo yoo le; 1. Salaye onaa ti awon kan n gba fi omonikeji won seru ati ilokulo omo lode oni | Awon to n lo omo ni ilokulo lode oni yala omo won tabi omo elomiran | aworan | 1. Salaye ise yii fawon akekoo 2. Beere ibeere | 1. teti salaye oluko 2. Beere ibeere 3. Se adako ohun ti oluko ko soju patako | |
| D | litireso | Asayan iwe ewi | Akekoo yoo le; 1. kewi naa dan-moran 2. se idamo onaa ede ati isowolo ede | 1. Ewi kike 2. koko oro a jemo oro to n lo | Aworan | 1. kewi naa fun awon akekoo. 2. Salaye kikun lori ewi ti a ke | 1. Kewi naa bi I ti oluko 2. Toka si onaa ede ati isowolo ede inu ewi | Iwe ewi ti ijoba yan |
| 12 | A.   Ede B. Litireso  D. Asa | Atunyewo eko | Sise atunyewo eko | |||||
| 13 | A.   Ede  B. Litireso  D. Asa | Idanwo asekagba JSS 3 (Idanwo ijoba) JSSSCE |